score
float32 1.04
1.25
⌀ | Tigrinya
stringlengths 9
461
⌀ | Yoruba
stringlengths 9
499
|
---|---|---|
1.248958 |
እዚ ድማ ጽድቂ እዩ።
|
Eyi ni ododo kan ti tan jade.
|
1.244718 |
እቲ ምሳይ ዚዛረብ ዝነበረ መልኣኽ ከኣ፡ "እዚኣቶም መን ከም ዝዀኑ ኸርእየካ እየ" በለኒ።
|
Angẹli tí ń ba mi sọ̀rọ̀ sì wí fún mi pé, "Èmi ó fi ohun tí àwọn wọ̀nyí jẹ́ hàn ọ́."
|
1.244056 |
ፍቓድ እቲ ኣብ ሰማይ ዘሎ ኣቦይ ዝገብር ኲሉ ንሱ ሓወይን ሓፍተይን እኖይን እዩ በለ።
|
Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe ìfẹ́ Baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run, òun ni arakunrin mi ati arabinrin mi ati ìyá mi.
|
1.242103 |
ብሰንኪ ብዝሒ ክፍኣት ከኣ ፍቕሪ ብዙሓት ክትዝሕትል እያ።
|
Nítorí pé ìwà ìbàjẹ́ yóo gbilẹ̀, ìfẹ́ ọpọlọpọ yóo rẹ̀wẹ̀sì.
|
1.240419 |
እቲ ዘይበልዕውን ንጐይታ ኢሉ እዩ ዘይበልዕ፡ ንኣምላኽ ከኣ የመስግኖ።
|
Ẹni tí kò jẹ, kò jẹ ẹ́ nítorí Oluwa, ọpẹ́ ni òun náà ń fi fún Ọlọrun.
|
1.240182 |
ሙሴ እዚ ምስ ሰምዔ፡ ብገጹ ተደፍኤ።
|
Nígbà tí Mose gbọ́, ó dojúbolẹ̀,
|
1.23997 |
29 (፳፱) ጻድቃን ንሃገር ኪወርስዋ፣ ኣብኣውን ንዘለኣለም ኪነብሩ እዮም።
|
29 Olododo ni yio jogun aiye, yio si ma gbe inu rẹ̀ lailai.
|
1.236497 |
ኣብ ኣዒንትኹም ጽቡቕን ቅኑዕን ዝመሰለኩም ግበሩኒ።
|
Ṣe fún mi ohun tí ó dára tí ó sì tọ̀nà lójú rẹ.
|
1.236073 |
ስለዚ እዛ ዓለም ኃያል ኢድ ጥራሕ ዘቀመጣ ፍጥረት ኣይኮነትን፡ ጥበበኛ ኢድ ዘቐመጣ፡ ናይ ጥበበኛ ዓሸራ ዝንበበላ ናይ ሕይወት መጽሓፍ ውን እያ"።
|
O ko nikan ni ifarahan didara, ṣugbọn o tun jẹ ọlọgbọn.
|
1.23553 |
3ንሱ ድማ፦ ኣነውን ሓንቲ ነገር ክጥይቐኩም ንገሩኒ።
|
3 O si dahùn o si wi fun wọn pe, Emi pẹlu yio si bi nyin lẽre ọ̀rọ kan; ẹ sọ fun mi.
|
1.234509 |
"እስከ ንገረና፡ እዚ መዓስ ኪኸውን እዩ፧"
|
"Sọ fún Wa, Ìgbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹlẹ̀?"
|
1.22949 |
የሱስ፡ "እቲ ኽሳዕ መወዳእታ ዚጻወር ግና ኪድሕን እዩ" በለ።
|
Jésù sọ pé: "Ẹni tí ó bá fara dà á dé òpin ni ẹni tí a ó gbà là."
|
1.228712 |
ህዝብኻ ኣብ ኣኽራን ፋሕ ኢሎም ኣለዉ፣ዚእክቦም ከኣ ሓደ እኳ የልቦን።
|
Awọn enia rẹ ti wà farasin ninu awọn òke, ati nibẹ ni ko si ọkan lati kó wọn.
|
1.227762 |
13 - ኣብ ማእከልኩምከ ለባምን ኣስተውዓልን መን እዩ፧ ንሱ ብሰናይ ኣኻይዳኡ ብለውሃት ጥበብ ገይሩ ግብሩ የርኢ።
|
13 Tani ọlọgbọn ti o ni oye pẹlu larin yin? jẹ ki i ṣafihan awọn iṣẹ rere rẹ pẹlu irẹlẹ ti ọgbọn.
|
1.227308 |
ጽድቁ ኽርኢ እየ።
|
èmi yóò sì rí òdodo rẹ̀.
|
1.223452 |
ንሱ ኸኣ ከተማ ሰርሔ፡ ስም እታ ኸተማ ድማ ብስም ወዱ ሄኖክ ኣውጽኣላ።
|
O si kọ ilu kan, o si pe orukọ rẹ̀ ni orukọ ọmọ rẹ̀, Enọku.
|
1.223203 |
14 ንሱ ኸኣ መቕደስ ኪኸውን እዩ፣
|
14 Òun yóò sì jẹ́ ibi mímọ́
|
1.222892 |
33እምበኣርከስ ሸውዓቲኦም ኣእትዮምዋ ነይሮም እዮም እሞ እታ ሰበይቲ እቲኣ ብትንሣኤ ሙታን ሰበይቲ ኣይንኦም ክትከውን እያ?
|
33 Njẹ li ajinde okú, aya titani yio ha ṣe ninu wọn? nitori awọn mejeje li o sá ni i li aya.
|
1.222654 |
ማኖኣ ድማ ንሰበይቱ፡ ንኣምላኽ ርኢናዮ ኢና እሞ፡ ብርግጽ ክንመውት ኢና፡ በላ።
|
Manoa bá sọ fún iyawo rẹ̀ pé, "Dájúdájú, a óo kú, nítorí pé a ti rí Ọlọrun.
|
1.222558 |
ንሱ ኸኣ፡ "ሰማያዊ ኣቦይ ዘይተኸሎ ዘበለ ተኽሊ ኺምንቈስ እዩ።
|
Jesu dá wọn lóhùn pé, "Gbogbo igi tí Baba mi tí ń bẹ lọ́run kò bá gbìn ni a óo hú dànù.
|
1.222356 |
10 ከምዚ ድማ በለኒ፦ "እቲ ምዱብ ግዜ ቐሪቡ እዩ እሞ፡ ንቓል ትንቢት እዛ ጥቕልልቲ መጽሓፍ እዚኣ ኣይትሕተሞ።
|
Ó tún sọ fún mi pé, "Má ṣe fi èdìdì di àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ ìwé yìí nítorí àkókò tí wọn yóo ṣẹ súnmọ́ tòsí.
|
1.219501 |
አነ ብማይ የጠምቐኩም አሎኹ፥ ንሱ ግና ብመንፈስ ቅዱስ ኬጠምቐኩመዩ" እናበለ ይሰብኽ ነበረ።
|
8Èmi ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi yín, ṣùgbọ́n Òun yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe ìtẹ̀bọmi yín."
|
1.21933 |
25ዕሽነት እግዚኣብሔር መሲሉ ዝርአ ካብ ፍልጠት ሰብ ይበልጽ እዩ፤ ድኻም እግዚኣብሔር መሲሉ ዝርአ ኸዓ ካብ ኃይሊ ሰብ ይብርትዕ እዩ።
|
25 Nitoripe wère Ọlọrun gbọ́n jù enia lọ; ati ailera Ọlọrun li agbara jù enia lọ.
|
1.218164 |
እቲ እምኒ ኸዓ፣ ካብቲ መቓብር ተንከባሊሉ ረኸባኦ።
|
Wọ́n rí i pé wọ́n ti yí òkúta kúrò ní ẹnu ibojì.
|
1.217986 |
ካብ ጸልማት እተጸውዑ
|
A Mú Wọn Jáde Kúrò Nínú Òkùnkùn
|
1.216772 |
15እዙይ ድማ በቲ ዝረአኻዮን ዝሰማዕኻዮን ኣብ ኲሉ ሰብ ምስክር ምእንቲ ኽትኮኖ እዩ።
|
15 Nitori iwọ yoo ṣe ẹri rẹ si gbogbo eniyan ti ohun ti o ti rii ati ti gbọ.
|
1.216729 |
ነቦይ ምልማኑ ዘይከኣለኒ፡ ንሱ ኸኣ ካብ ዓሰርተው ክልተ ለጌዎን ዚበዝሑ መላእኽቲ ሕጂ ኺሰደለይ ዘይኽእልዶ ይመስለካ አሎ፧
|
Tabi o kò mọ̀ pé mo lè ké pe Baba mi, kí ó fún mi ní ẹgbaagbeje angẹli nisinsinyii?
|
1.216644 |
እቲ እከይ ዚገብር፡ ንኣምላኽ ኣይረኣዮን።
|
Ẹnikẹni ti o ba nṣe buburu kò ri Ọlọrun.
|
1.216346 |
ብሰንኪ ብዝሒ ክፍኣት ካኣ ፍቕሪ ብዙሓት ክትዝሕትል እያ።
|
Nítorí pé ìwà ìbàjẹ́ yóo gbilẹ̀, ìfẹ́ ọpọlọpọ yóo rẹ̀wẹ̀sì.
|
1.216046 |
ስለዚ፡ "ብዘይካ ንሒደት ሕሙማት ኣእዳዉ ኣንቢሩ ዘሕወዮም" እምበር፡ ኣብኡ ተኣምራት ኣይገበረን።
|
Kò lè ṣe iṣẹ́ ìyanu níbẹ̀ àfi pé ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé àwọn aláìsàn bíi mélòó kan, a sì wò wọ́n sàn.
|
1.215858 |
ሓደ ምስላ ድማ ነገሮም፥ ኣብ ኦም በለስን ኣብ ኵሉ ኦምን ርኣዩ።
|
Ó pa òwe kan fún wọn, ó ní, "Ẹ wo igi ọ̀pọ̀tọ́ ati gbogbo igi yòókù.
|
1.215807 |
ንሱስ ምስጢራት ልቢ ይፈልጥ እዩ።
|
Nitori ti o mọ awọn asiri ti ọkàn.
|
1.214772 |
ቤት ያእቆብ እውን ርስቶም ኪርስተዩ እዮም።
|
àti ilé Jakọbu yóò sì ní ìní wọn
|
1.214517 |
13ኲሉ ነገር እንተ ደኣ ናብ ብርሃን ቀሪቡ ግና ይርአ፤ እቲ ንዂሉ ከም ዝርአ ዝገብር ከዓ ብርሃን እዩ።
|
13 Ṣugbọn ohun gbogbo ti a mba wi ni imọlẹ ifi han: nitori ohunkohun ti o ba fi nkan hàn, imọlẹ ni.
|
1.214362 |
ንሱ እግዚኣብሄር ኣምላኽና እዩ፣ ፍርዱ አብ ኵሉ ምድሪ እዩ።
|
Òun ni OLUWA Ọlọrun wa,ìdájọ́ rẹ̀ ká gbogbo ayé.
|
1.214129 |
ሕሙማት ኬሕውዩ ኣጋንንቲውን ኬውጽኡ ድማ፡ ስልጣን ሀቦም።
|
kí wọn lè ní àṣẹ láti máa lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.
|
1.213705 |
17 ደቅኺ ቐልጢፎም ይምለሱ።
|
17 Àwọn ọmọ rẹ ti kánjú padà,
|
1.213344 |
32 ንሓድሕዶም ከኣ፡ "ኣብ መገዲ ኺዛረበናን ነቲ ቕዱሳት ጽሑፋት ብንጹር ኪገልጸልናን ከሎዶ ግዳ ልብና ኣብ ውሽጥና ይነድድ ኣይነበረን፧" ተባሃሃሉ።
|
32 Nwọn si ba ara wọn sọ pe, Ọkàn wa kò ha gbiná ninu wa, nigbati o mba wa sọ̀rọ li ọna, ati nigbati o ntumọ̀ iwe-mimọ́ fun wa?
|
1.212701 |
15እዝ ዂሉ ንጥቕምኹም እዩ፤ ምኽንያቱ ብዙኅ ጸጋ ኣብ ብዙኃት ሰባት ክብርክት እንተሎ እቲ ንኽብሪ እግዚኣብሔር ዝዓርግ ምስጋና ኽበዝኅ እዩሞ።
|
Nítorí tiyín ni gbogbo èyí, kí oore-ọ̀fẹ́ lè máa pọ̀ sí i fún ọpọlọpọ eniyan, kí ọpẹ́ yín lè máa pọ̀ sí i fún ògo Ọlọrun.
|
1.211556 |
ኣየ: ትእዛዛተይ ሰሚዕካ እንተ ትኸውንሲ: ሰላምካ ኸም ወሓዚ: ጽድቅኻውን ከም ማዕበል ባሕሪ ምዀነ ነይሩ።
|
"Ìbá jẹ́ pé o ti fetí sí òfin mi,alaafia rẹ ìbá máa ṣàn bí odò,òdodo rẹ ìbá lágbára bi ìgbì omi òkun.
|
1.211393 |
ሽዑ ጲላጦስ ንስካትኩም ውሰድዎ፡ ከምቲ ሕግኹም ጌርኩምውን ፍረድዎ፡ በሎም።
|
31 Nítorí náà Pilatu wí fún wọn pé, "Ẹ mú un tìkára yín, kí ẹ sì ṣe ìdájọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òfin yín."
|
1.21078 |
ንሱ ንሓዋሩ* ኺመርሓና እዩ።
|
Òun ni yóo máa ṣe amọ̀nà wa títí lae.
|
1.210686 |
በቲ ንሱ ዝለኣኾ ስለ ዘይኣመንኩም ከኣ ቓሉ ኣባኹም ኣይኃደረን።
|
Ẹ kò jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ gbé inú yín nítorí ẹ kò gba ẹni tí ó rán níṣẹ́ gbọ́.
|
1.21026 |
ኵሎም ሰባት ጽቡቕ ምስ ዚዛረቡልኩም፡ ኣቦታቶም ንናይ ሓሶት ነብያት ከምኡ ገይሮምዎም እዮም እሞ፡ ወይለኹም።
|
"Nígbà tí gbogbo eniyan bá ń ròyìn yín ní rere, ẹ gbé, nítorí bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba wọn ṣe sí àwọn èké wolii.
|
1.209917 |
ካብ ኵሉ ጭንቁ ኸኣ ኣድሒንዎ።
|
ó sì gbà á là kúrò nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀.
|
1.209531 |
29ንሱ ኸዓ እዝ ኸምዙይ ዝዓይነቱ ርኹስ መንፈስ ብጾምን ብጸሎትን እንተ ዘይኮይኑ ኣይወፅእን እዩ፤ በሎም።
|
29 O si wi fun wọn pe, Irú yi kò le ti ipa ohun kan jade, bikoṣe nipa adura ati àwẹ.
|
1.209526 |
ብርታዐኻን ክብርኻን ድማ ርእየ።
|
mo rí agbára àti ògo rẹ.
|
1.209092 |
18ኣነ ነዘ ኣብዘ መጽሓፍ እዙይ ዘሎ ቓል ትንቢት ንዘሰምዑ ዂሎም አጠንቅቖም ኣለኹ፦ ሓደኳ ናብዘን ቃላት እዚኣተን እንተ ወሰኸ እግዚኣብሔር ከዓ ኣብዘ መጽሓፍ እዙይ ተጽሒፉ ዘሎ መቕሠፍቲ ኽዉስኸሉ እዩ።
|
18 Nitori mo jẹri fun gbogbo enia ti o gbọ ọrọ asọtẹlẹ ti iwe yi pe, Bi ẹnikan ba fi kún nkan wọnyi, Ọlọrun yio fi kún u iyọnu ti a kọ sinu iwé yi:
|
1.20827 |
9 እምበኣር፡ ንህዝቢ ኣምላኽ ዕረፍቲ ሰንበት ተሪፋትሎም ኣላ።
|
9 Nitorina isimi kan kù fun awọn enia Ọlọrun.
|
1.207371 |
መሰረታት ምድሪ ዚነግርዎዶኸ ኣየስተውዐልኩምን ኢኹም?
|
Njẹ o ko loye awọn ipilẹ ilẹ?
|
1.20686 |
እዚ ግና ንስኻትኩም ምእንቲ ኽትድኅኑ ኢለ እየ ዝብሎ ዘሎኹ እምበር ኣነስ ምስክር ሰብ ዝቕበል ኣይኮንኩን።
|
345.34: 1Jh 5.9.Ṣùgbọ́n èmi kò gba jẹ́rìí lọ́dọ̀ ènìyàn: nǹkan wọ̀nyí ni èmi ń sọ, kí ẹ̀yin lè là.
|
1.206364 |
ዝገበርኩምሎም'ዩ ዝገበርኩምለይ 27.
|
Ẹ Ti Ṣe É fún Mi 27.
|
1.20599 |
18 ጸዊዖም ድማ፡ ብስም የሱስ ንሓደ እኳ ኸይዛረቡ ወይ ከይምህሩ ኣዘዝዎም።
|
4:18 Ati pipe wọn wọle, wọn kilọ fun wọn lati maṣe sọrọ tabi kọni rara rara ni orukọ Jesu.
|
1.205905 |
ንስኻትኩም ሕርሻ ኣምላኽ፡ ህንጻ ኣምላኽ ኢኹም።
|
Iwọ ni ogbin Ọlọrun; iwo ni ikole Olorun.
|
1.205408 |
ታሕሳስ 2013 ኣምላኽ የድልየና ድዩ፧
|
DECEMBER 2013 Ǹjẹ́ A Nílò Ọlọ́run?
|
1.205402 |
እቲ ሓይሊ ዜዕጥቐኒ፣ ንመገደይ ከኣ ዜቕንዓ ኣምላኽ" (መ.
|
Ọlọrun tí ó gbé agbára wọ̀ mí,tí ó sì mú ọ̀nà mi pé.
|
1.204293 |
6 2017 _ ዓለም ካብ ቍጽጽር ወጻኢ ድያ እትኸውን ዘላ፧
|
No. 6 2017 | Ṣé Ayé Yìí Ti Bà Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe?
|
1.203851 |
ርስቲ እቶም ስምካ ዚፈርሁ ሂብካኒ ኣለኻ።
|
Ìwọ ti fún mi ní ogún àwọn tí ó bẹ̀rù orúkọ rẹ.
|
1.202958 |
ኣብ ጭንቂ እየ ዘለኹ እሞ፡ ቀልጢፍካ መልሰለይ።
|
yára dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú.
|
1.202465 |
14ወይ ከዓ ሰብኣይ ፀጕሩ እንተንወኀ ነውሪ ምዃኑስ እቲ ተፈጥሮ ባዕሉዶ ኣይምህረኩምን እዩ?
|
14 Ani ẹda tikararẹ̀ kò ha kọ́ nyin pe, bi ọkunrin ba ni irun gigun, àbuku ni fun u?
|
1.20215 |
ኣእዳዉ እውን ንንቑጽ ምድሪ ገበራኦ።
|
àti ọwọ́ rẹ̀ ni ó fi dá ìyàngbẹ ilẹ̀.
|
1.201943 |
ልባርከ ፡ ጌታዬን
|
Getaye Getaye ጌታዬ My lord
|
1.201719 |
መንበሪኡ እውን ኣብ ጽዮን እዩ።
|
Ati ibugbe rẹ ibi ni ni Sioni.
|
1.200928 |
ኣብ ቤተይን ኣብ መንግስተይን ደኣ ንዘለኣለም ከቚሞ እየ፡ ዝፋኑ ኸኣ ንዘለኣለም ኪጸንዕ እዩ።
|
N óo fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ ní ilé mi ati ninu ìjọba mi títí lae.
|
1.200837 |
"እታ መገዲ እዚኣ እያ" 55.
|
"Èyí Ni Ọ̀nà" 55.
|
1.200747 |
13 ብርግጽ፣ ጻድቃን ንስምካ ኼማስዉ፣ ቅኑዓት ኣብ ቅድሜኻ ኺነብሩ እዮም።
|
13 Nitõtọ awọn olododo yio ma fi ọpẹ fun orukọ rẹ: awọn ẹni diduro-ṣinṣin yio ma gbe iwaju rẹ.
|
1.200518 |
ንሱ ኣብ ቤት ያእቆብ ንዘለኣለም ኪነግስ እዩ፡ መንግስቱ ኸኣ መወዳእታ የብላን።
|
Yóo jọba lórí ìdílé Jakọbu títí lae, ìjọba rẹ̀ kò ní lópin.
|
1.200413 |
30 ንሱ ነቢይ ስለ ዝነበረ እግዚኣብሔር ሓደ ካብ ፍረ ኸርሡ ኣብ ዝፋኑ ኸቐምጥ ማሕላ ኸም ዝመሓለሉ ይፈልጥ ነበረ።
|
2:30 Nitorina, o si wà kan woli, nitoriti on mọ pé Ọlọrun ti bura bura fun u nipa eso ẹgbẹ rẹ, nipa awọn ẹniti o yoo joko lori itẹ rẹ.
|
1.200255 |
26ንስኻትኩም ግና ኸምኡ ኣይትኹኑ፤ ኣባኻትኩም እቲ ዓብዪ ኸም ንእሽተይ እቲ ሓለቓ ክኸውን ዝደሊ ኸም ኣገልጋሊ ይኹን።
|
26 Ṣugbọn ẹnyin kì yio ri bẹ̃: ṣugbọn ẹniti o ba pọ̀ju ninu nyin ki o jẹ bi aburo; ẹniti o si ṣe olori, bi ẹniti nṣe iranṣẹ.
|
1.199734 |
ከም ውጽኢቱ ከኣ ሸሞንተ ብረት መሳርሒታት ጽሕፈት፣
|
Ewa adalu ti awọn ata - awọn ege awọn ege mẹjọ;
|
1.199527 |
(ኢሳይያስ 46:10) ንስኻን ስድራ ቤትካን ዜደንቕ መጻኢ ኺህልወኩም ይኽእል እዩ።
|
(Aísáyà 46:10) Ọjọ́ ọ̀la aláyọ̀ ń dúró de ìwọ àti ẹbí rẹ.
|
1.199388 |
ወዲ ሰብ ግና ካብ ሕጂ ኣብ የማን ሓይሊ ኣምላኽ ኪቕመጥ እዩ፡ በሎም።
|
Láti àkókò yìí, Ọmọ-Eniyan yóo jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọrun Olodumare.
|
1.19927 |
"ገሌኻትኩም ከኣ ከማታቶም ኔርኩም ኢኹም"
|
"Ohun Tí Àwọn Kan Lára Yín Ti Jẹ́ Rí Nìyẹn"
|
1.199016 |
ኣምላኽ እውን ነቶም ነብሶም ዝሕግዙ እኳ እዩ ዝሕግዝ።
|
" Ati pe dajudaju Ọlọhun yoo maa se iranlọwọ fun ẹni ti i ba n ran AN lọwọ " [Suuratul-Hajj: 40].
|
1.198712 |
6 ደጊም ብጊዜኡ ንሱ ልዕል ምእንቲ ኼብለኩም፡ ኣብ ትሕቲ እታ ጽንዕቲ ኢድ ኣምላኽ ትሕት በሉ።
|
6 Nitorina ẹ rẹ̀ ara nyin silẹ labẹ ọwọ́ agbara Ọlọrun, ki on ki o le gbé nyin ga li akokò.
|
1.198706 |
እኩይ ብግብሪ ኣእዳዉ ተፈንጢሩ ኣሎ።
|
àwọn ènìyàn búburú ni a dẹ́kun mú nípa iṣẹ́ ọwọ́ wọn.
|
1.198699 |
እምብኣርስኸ ንዝደለዮ ይምሕሮ፡ ንዝደለዮውን የትርሮ እዩ።
|
È ñå Ìîñîìàõú ñëûøàâú îò âëúõâà, ñêîðî ëóêú ñâîè ïðèíåñå, óñòðѣëè ïòîòó.
|
1.198123 |
"ሓይሊ ንጉስ ድማ ፍርዲ (ፍትሒ) ይፈቱ እዩ፣ ንስኻ ቕንዕና ኣጽናዕካ፣ ፍርድን ጽድቅን ኣብ ቤት ያእቆብ ገበርካ።
|
Ọba alágbára, ìwọ tí o fẹ́ràn òdodo,o ti fi ìdí ẹ̀tọ́ múlẹ̀;o ti dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ ati òdodo ní ilẹ̀ Jakọbu.
|
1.197311 |
እግዚኣብሔር ብቃሉ ይዛረበና።
|
Ṣugbọn ranti pé Ọlọrun sọrọ si wa nipasẹ ọrọ rẹ.
|
1.196796 |
እቲ ምስ ፈርኦን ኪዛረቡ ኸለዉ ኸኣ፡ ሙሴ ወዲ ሰማንያ ዓመት፡ ኣሮን ድማ ወዲ ሰማንያን ሰለስተን ዓመት ኰይኖም ነበሩ።
|
7 Mose jẹ́ ẹni ọgọrin ọdún, Aaroni si jẹ́ ẹni ọgọrin ọdún o le mẹta, nigbati nwọn sọ̀rọ fun Farao.
|
1.196303 |
ኣምላኽ ካብ መዋቲ ሰብ ኣጸቢቑ ይዓቢ እዩ።
|
Ọlọ́run ju ẹ̀dá lọ - Wike
|
1.196011 |
በታ መዓልቲ እቲኣ ኸኣ ልቢ እቶም ጀጋኑ ኤዶም ከም ልቢ ቅልውላው ዝሓዛ ሰበይቲ ኪኸውን እዩ።
|
Ati ni ọjọ ti, okan ti awọn alagbara Moabu yio dabi ọkàn obinrin kan fifun ni ibi.
|
1.195955 |
ነቦይ ምልማኑ ዘይከኣለኒ፡ ንሱ ኸኣ ካብ ዓሰርተው ክልተ ለጌዎን ዚበዝሑ መላእኽቲ ሕጂ ኺሰደለይ ዘይኽእልዶ ይመስለካ አሎ፧
|
53Ìwọ kò mọ̀ pé èmi lè béèrè lọ́wọ́ Baba mi kí ó fún mi ju légíónì (6,000) angẹli méjìlá?
|
1.195921 |
) እዚ እቲ ቐዳማይ ትንሳኤ እዩ።
|
ni yoo kọkọ jinde.
|
1.195653 |
ኣብቲ ገዛ ኣቦይ ክህሉ ኸም ዝግብአኒዶ ኣይትፈልጡን ኢኹም?
|
Ẹ kò mọ̀ pé dandan ni fún mi kí n wà ninu ilé Baba mi?
|
1.195525 |
ኣብቲ ግዜ እቲ፡ ህዝቢ ኣምላኽ ደገፍን ዕቝባን የድልዮም ነይሩ።
|
Àwọn èèyàn Ọlọ́run nílò ìrànlọ́wọ́ àti ààbò gan- an.
|
1.195469 |
ከምዚ ድማ በለ፦ "ከምቲ ብዘመን ኖህ ዝዀነ፡ ወዲ ሰብ ኣብዚ ኣብ ዚህልወሉ እዋን [ወይ፡ ዳሕሮት መዓልትታት] ከኣ ከምኡ ኪኸውን እዩ።
|
Àní bí ó ti rí ní àkókò Noa, bẹ́ẹ̀ ni yóo rí nígbà tí Ọmọ-Eniyan bá dé.
|
1.195365 |
ኦ ይሁዳ፡ ኣማልኽትኻ ኸም ከተማታትካ ብዙሓት ኰይኖም እዮም እሞ፡
|
Ṣebí bí ìlú yín ti pọ̀ tó, bẹ́ẹ̀ ni àwọn oriṣa yín náà pọ̀ tó, ẹ̀yin ará Juda.
|
1.195265 |
ነቲ ድኻ ሰብኣይ ግና ሓደ እኳ ኣይዘከሮን።
|
Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó rántí ọkùnrin tálákà náà.
|
1.195219 |
እቶም ዚጸልእዎ ድማ ካብ ቅድሚኡ ይህደሙ።
|
Ati awọn ti o korira wọn di alaṣẹ lori wọn.
|
1.195103 |
18ኣትን ኣንስቲ ንእግዚኣብሔር ደስ ብዘብል መንገዲ ንሰብኡትክን ተኣዘዛኦም።
|
18 Ẹnyin aya, ẹ mã tẹriba fun awọn ọkọ nyin, gẹgẹ bi o ti yẹ ninu Oluwa.
|
1.195047 |
ንሳቶም ግና አዝዮም ነደሩ፥ ንኢየሱስ እንታይ ከም ዚገብርዎ ድማ ንሓድሕዶም ተማኸሩ።
|
Inú wọn ru sókè, wọ́n wá ń bá ara wọn jíròrò nípa ohun tí wọn ìbá ṣe sí Jesu.
|
1.194775 |
ሰፈርካ እውን ኣብ መንጎ ኸዋኽብቲ እንተ ትገብር፡
|
bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárín àwọn ìràwọ̀,
|
1.194762 |
ንቤት ኣሮን ኪባርኻ እዩ፣
|
yóò bùkún ilé Aaroni.
|
1.194711 |
ብዙሕ ህዝቢ ኸኣ ናብ ጐይታ ተወሰኸ።
|
Ati pe ọpọlọpọ eniyan ni a fi kun si Oluwa.
|
1.194696 |
እከይ ግብርኹም ካብ ቅድሚ ኣዒንተይ ኣርሕቕዎ፣
|
Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi!
|
1.194675 |
ናቶም ፍልጠት እዩ ኣዕብይዎ።
|
Nítorínáà, wọ́n ní ìmọ̀ tí ó ga gẹ́gẹ́ bí ìṣẹ̀dá wọn.
|
1.193737 |
ከነኣን ድማ ባርያኡ ይኹን።
|
ẹrú rẹ̀ ni Kenaani yóo máa ṣe.
|
1.193428 |
ብልሳኖም እውን ሓሰውዎ።
|
wọ́n fi ahọ́n wọ́n purọ́ fún un;
|
1.193333 |
ኣቦይ እውን ነዚ ይፈልጦ እዩ' በሎ።
|
Ati pe baba mi paapaa mọ eyi. "
|
Tigrinya-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Tigrinya-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 133381
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Tigrinya, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score
: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Tigrinya
: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba
: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 13